Awade Lyrics – FOLA

Awade Lyrics - FOLA

[Intro]
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
Èmi náà kọ́, Ọlọ́run Ọba mi
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
(Tune in—)

[Chorus]
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀? (Boss)

[Verse 1]
Torí kí n lè make ẹ̀, mo ṣe sá nílé
Ah, mo mọ̀ pé ó ń gb’óhùn mi from miles away
Ah, Yahweh, Yahweh, jọ̀wọ́ bá mi ṣe (Ooh)
To avoid the banter, mo ń calculate

[Pre-Chorus]
Ah, mi ò mọ̀ pé ojú ogun le, ń bá ti gbé bazooka
I saw some shege, àánú ṣáà ni mo ń rí gbà
So, Ẹlẹ́dàá mi, mo bẹ̀bẹ̀
Ibi t’ọ́n wa moto, kí n má lọ lo keke
I for don die, ọpẹ́lọpẹ́ mo rí jà

[Chorus]
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀?

[Verse 2]
I don’t know, oh, I don’t know
Ọmọ ń gb’àdúrà
K’ọ́n ma kó mi jẹ bí Yàkọ́yọ̀
Kí (??) matter mi bí t’Àbólò

K’ọ́n fun wọn tó ní (??)
All I need is my own, oh

[Pre-Chorus]
Ah, mi ò mọ̀ pé ojú ogun le, ń bá ti gbé bazooka
I saw some shege, àánú ṣáà ni mo ń rí gbà
So, Ẹlẹ́dàá mi, mo bẹ̀bẹ̀
Ibi t’ọ́n wa moto, kí n má lọ lo keke
I for don die, ọpẹ́lọpẹ́ mo rí jà

[Chorus]
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀?

[Intro]
Àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀, àwa dé o
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé’bẹ̀?

Awade Song Credits & Production Details

Song Title Awade
Album 9
Singer(s) FOLA
Musician(s) Magicsticks & Sbthaproducer
Lyricist(s) FOLA, Sbthaproducer & Magicsticks
Release Date October 9, 2026
Label Dangbana Republik
Copyright © Dangbana Republik & EMPIRE
Language English

More Lyrics from “9” Album

9

FOLA • October 9, 2026

Frequently Asked Questions About Awade Song

Who is the singer of the song ‘Awade’?

The song ‘Awade’ is sung by FOLA.

Who wrote the song ‘Awade’ by FOLA?

The song ‘Awade’ by FOLA is written by FOLA, Sbthaproducer and Magicsticks.

Who produced the music for the song ‘Awade’?

Music of the song ‘Awade’ is produced by Magicsticks and Sbthaproducer.

When was the song ‘Awade’ officially released?

The song ‘Awade’ is officially released on October 9, 2026, accompanied by its official music video.

What album is the song ‘Awade’ from?

The song ‘Awade’ is from the album titled ‘9’.

Which record label released the song ‘Awade’?

The song ‘Awade’ by FOLA was released under the record label Dangbana Republik.

Who owns the copyright of the song ‘Awade’?

Dangbana Republik and EMPIRE own the copyright of the song ‘Awade’.

More Lyrics for You

Disclaimer

“This concludes the lyrics of Awade” by FOLA. The lyrics shown here are intended purely for educational use. We honor the work of artists and stand against copyright infringement. If this song resonates with you, please show your support by engaging with the original creators.

If you find any errors in it, please feel free to submit the correct version via the Contact Us section.